Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 225

Gbogbo eniti ongbe ngbe, e wa sibi omi

Meter: C.M.

Scripture: Isa. 55:1

1

E yin t’ ongbe ngbe, e wa mu

Omi iye ti nsan;

Lati orisun ti Jesu

Laisanwo l ’ awa nbu.

2

pWo! b’o ti pe to t’e ti nmu

Ninu kanga eke

T’e nl’agbara at’ogun yin

crNinu nkan t’o nsegbe.

3

Jesu wipe, isura Mi,

Ko lopin titi lae

Yio filera laelae fun

Awon t’o gbo Tire