Hymn 23
Emi o dubule pelu li alafia, emi o si sin.
Meter: L.M
Scripture: OD 4:8
1
mfIwo imole okan mi,
Ni odo Re, oru ko si,
Ki kuku aye ma bo O,
Kuro l’oju iranse Re.
2
ppNi gbat’orun ale didun
Ba npa ipenpe ‘ju mi de,
K’ero mi je lati simi,
Lae l’aya Olugbala mi.
3
mfBa mi gbe l’oro tit’ale
Laisi Re, emi ko le wa,
PBa mi gbe ‘gbat’ile ba nsu,
Laisi Re, emi ko ke ku.
4
mpBi otosi omo Re kan
Ba tapa s’oro Re loni,
CrOluwa, sise ore Re,
Ma je k’o sun ninu ese
5
mfBukun fun awon alaisan,
Pese fun awon talaka,
DiK’orun onirobinuje
PpDabi orun omo titun
6
crSure fun wa ni gbat’a ji
Ka to m’ohun aye yi se
FTiti awa de ‘b’ife
Ta o si de Ijoba Re.