Hymn 237
Sa wo o, awa to O wa nitori IWO li Oluwa Olorun wa.
Meter: 8.8.8.D.
Scripture: Jer. 3:22
1
mpO su mi lati ma sako,
O toge, uno wa Olorun;
Mo teriba fun opa Re,
Fun O, mo ns’ofo n’nu ’reti,
crMo n’ Alagbawi kan l’oke,
Ore niwaju ’te ife
2
mfA! Jesu t’o kun f or’-ofe
Ju bi mo ti kun fun ese,
Lekan si mo tun nwo ’ju Re
N’apa Re si gba mi mo ’ra
L’ofe wo faseyin mi san;
Fe em’ alaigbagbo sibe
3
mp’Wo m’ona lati pe mi bo,
Lati gb’ eni t’o subu ro;
A! tor’ anu at’oto Re
Dariji, ma je ki n’se mo,
crTun ibaje okan mi se,
Ko si se n’ile adura
4
mpA! fun mi ni kan riro
Ti y’o ma wa riri f’ese,
Fun mi ni iberu f’ese
Mu ko ta gbongbo ninu mi;
Ki nle beru agbara Re,
Ki nma tun d’ese si O mo.