Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 239

Enikeni ti o to mi wa, Emi kiyio ta a nu, bi o ti wu ko ri.

Meter: 8.8.8.6,

Scripture: Jn. 6:37

1

mpB i mo ti ri, lai s’awawi,

Sugbon nitori eje Re

B’ o si ti pe mi pe ki nwa;

pOlugbala, mo de.

2

Bi mo ti ri, laiduro pe,

Mo fe k’ okan mi mo toto,

S’odo Re to le we mi mo,

pOlugbala, mo de.

3

Bi mo ti ri, b’o tile je

Ija l’ode, ija ninu

pEru l’ode, eru ninu,

Olugbala, mo de.

4

diBi mo ti ri, osi are;

Mo si nwa imularada,

crIWO le s’awotan mi,

pOlugbala, mo de.

5

Bi mo ti ri ’WO o gba mi,

’Wo o gba mi, t’owo t’ese;

mf’Tori mo gba ’leri Re gbo;

pOlugbala, mo de.

6

mfBi mo ti ri ife Tire,

L’o sete mi patapata,

Mo di Tire, Tire nikan;

pOlugbala, mo de.

7

crBi mo ti ri, n’nu fe nla ni

T’o fi titobi Re han mi;

Nihin yi ati ni oke;

pOlugbala, mo de.