Hymn 249
Oluwa, sanu fun mi, nitori ailera mi.
Meter: 8.8.8.D.
Scripture: OD. 6:2
1
crOlorun mi, Olorun mi!
O to ge, nki o sako mo;
Nko ra eje Re mole mo,
Nko tun tan O ni suru mo;
diNko fa ’binu Re f’ese mo,
pNko dese si ife Re mo.
2
mfJesu, b’anu mbe lodo Re,
Da gbogbo re le mi lori;
crEmi olori elese,
T’o nm’ imi-edun f’anu Re,
Mu mi bo s’ or’-ofe Baba,
Ma jeki mbi O ninu mo.
3
Orisun ife ti ki gbe,
Jesu Abanikedun, gbo;
Olugbala mi li oke,
crS’Alagbawi mi l’ekan si,
F’ igbagbo on ’fiji fun mi;
mpJo jeki nyipada, ki nye!