Hymn 250
Emi o fe O, Oluwa agbara mi
Meter: L.M
Scripture: OD. 18:1
mfOlorun, kil 'emi y'o mi
Wa fi wole niwaju Re?
Kini uno ti ri l’oju Re?
Kini un o mu wa gb’ or’-ofe?
crEni nfe oju rere Re
Ko le se lair in lona Re;
K’o fe oto ati anu,
K’o f’igbagbo b’Olprun rin.
Mba je Tire lat’oni lo,
Ese mi atijo si mbe;
Bi mo f ohun gbogbo fun O
Tire ni mo fun O pada.
mfNje, kini mo le gbekele?
Nko l’ohun kan, asan ni mi,
Gbogbo fuja mi la sati
Itiju gbe ogo mi mi.
crMo j’elebi niwaju Re,
Lori mi n’ binu Re mbe;
pO to k’a je mi ni iya;
Oto; sugbon Jesu ti ku!
crJesu ti ta ’je Re sile,
O ru ese wa lor’ igi;
mpO teriba lab’ egun wa;
pO pari! O ti ku fun mi.
crWo t’o duro niwaju’te
O ngbadura ti y’o bori
O nf’iha, at’owo Re han,
Pe, a ko ’ruko mi sibe
O mbe laelae lati bebe;
Pe ki nle joba pelu Re
fAmin s’eyi t’Oluwa wi!
ffJesu ki O bebe lasan