Hymn 255
Eyi ha ise akoko ati gba fadaka ati lati gba ASO;
Meter: 7.6.7.6.D. & Ref.
Scripture: II A. Oba 5:26
1
mfAko fi oro ra mi,
Fadaka on wura,
Uno jijakadi f’orun,
Uno si wo ’nu agbo;
N’nu iwe Ijoba Re
Ti o Fewa pupo,
So fun mi Oluwa mi,
Oko mi ha wa nbe?
CHORUS
crOko mi ha wa nbe?
Ninu iwe nla ni
Iwe ti Ijoba Re
Oko mi ha wa nbe?
2
crOluwa, ese mi po,
Bi iyanrin okun.
Sugbon eje Re, Jesu
Ti to fun gbogbo re.
’Tori ’WO ti se’leri
Ninu oro Re pe;
”B’ese re pon b’ododo,
Un o fo won fun bi owu.”
3
fN’ilu daradara ni
At’ opo ’bugbe Re,
Nibit’ awon mimo wa
Nin’aso funfun won,
T’ohun eri ko le de
Lati b’ewa re je,
’Bi t’awon angeli nso,
Oko mi ha wa nbe?