Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 257

A won ti o ti gba opolopo ore Ore Ofe ati ebun ododo yio joba ninu iye.

Meter: C.M.

Scripture: Rom. 5:17

1

fOre-ofe! b’o ti dun to!

T’o gba em’ abosi;

crMo ti sonu, O wa mi ri,

O si si mi loju.

2

crOr’ofe ko mi ki m’beru,

O si l’eru mi LO

B’ore-ofe na ti han to

Nigba mo ko gbagbo!

3

mfOpo ewu at’ idekun

Ni mo ti la koja;

fOr’-ofe npa mi mo doni

Y’o si sin mi dele.

4

fLeyin aimoye odun n’be

T’a si nran bi orun,

Gbogb’ ojo tao fi ’yin Re

Y’o ju ’gba ’saju lo.