Hymn 26
Li osan pelu, o fi awosanma se amona Won ati li Oru Gbogbo pelu imole ina
Meter: 10.4.10.4.10.10
1
mp‘Wo imole larin okun aye,
Ma sin mi lo;
Okunkun su, mo si jinna s’ile,
Ma sin mi lo;
CrNko s’aferi ola bi y’o ti ri,
To ese mi, ‘sise kan to fun mi,
2
pNigba kan ri, emi ko be O pe
K’O sin mi lo,
Beni nko fe O, sugbon nigba yi,
Ma sin mi lo,
Afe aye ni mo si nto leyin,
Sungbon Jesu, ma ranti igba ni.
3
mfIpa Re l’o ti nid mi mu, y’o si Ma sin mi lo.
Ninu ere ati yangi aye,
Ma sin mi lo
Titi em’o fi ri awon wonni
Ti mo fe, ti won ti f’aye sile