Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 260

Awa ni alagbawi kan lodo Baba, Jesu Kristi Olododo.

Meter: 6.6.6.6.8.8.

Scripture: I Jn. 2:1

1

fDide, emi mi, nde

Gbon eru ebi re,

Eni t’a pa fun mi,

F’arahan n’tori mi:

Mo l’Onigbowo n’idi ’te,

A ko ’ruko mi S’OWO Re.

2

fO mbe l’oke laelae

Lati bebe fun mi,

On nf ife ’rapada

At’eje Re bebe,

diEje Re se ’tu gbogb' aye

O mbu won ile or’-ofe

3

pOgbe marun l'o gba

Li oke Kalfari;

crWon ngbadura aitase,

Won mbebe n’tori mi,

pWon nke, “Dariji, dariji''

Ma je k’elese na ko ku!

4

mpBaba gb’ebe eni

Ami ororo Re,

Ko le ko adura

Ti omo Re owon,

Emi Re ndahun ebe na

Pe, “Mo d’atunbi, Olorun”

5

mfMo b’Olorun laja,

crMo gb’ohun Tiji Re,

O SO mi d’omo Re,

Emi ko beru mo;

fMo fi ’gboya sunmo ’do Re,

Mo si nke pe, “Abba Baba.”