Hymn 262
Ki ise nipa ise ti awa se ninu ododo, sugbon gegebi anu Re li o gba wa la.
Meter: D.L.M.
Scripture: Titu 3:5
1
mfAjigbese opo anu,
Un o korin iyin anu Re,
fASO ododo Olorun
Ni mo gbe wO; eru ko si;
Ofin ko le da mi l’ebi,
Ore-Ofe so mi d’ominira,
Igboran Olugbala mi,
At’ eje Re, bo ese mi.
2
fIse rere t’oti bere,
Apa Re y’o se l’asepe;
Gbogbo ileri rere Re,
Beni, Amin! ni titi lae;
mfTani le ya wa ninu Krist’?
Ohun ti mbo, t’isisiyi?
Ko si l’aye, ko si l’orun
T’o le mu ipinu Re ye
3
fOruko mi mbe LOWO Re
Nko r’eni ti o le pare,
Ami or’ ofe lara mi,
Mo wa li okan aya Re;
Uno foriti titi d’opin,
Mo d’ohun ini Olorun,
Ayo orun mbe l’okan mi,
Pel’ awon t’a ti se Togo.