Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 263

Enyin si nyo ayo ti a ko lefi enu SO ti o si kunfun ogo.

Meter: 9.1.9.1. & Ref.

Scripture: I Pet. 1:8

1

crM o ti de ile ore-ofe

O to fun gbogb’ aini mi

Nigbati mo joko l’ese Re.

O si so mi d’ominira.

CHORUS

fAyo nla ni, ayo ti Jesu nfifun ni,

Ayo ti enu ko le so,

Ayo nla ni, ayo ti o kun fun ogo,

Ayo ti a ko le royin tan.

2

f‘Mo ti de ile igbadun nla,

Alafia mbe ninu mi;

Ibukun ti o kun wosile,

mpMo bo l’owo ese mi.

3

crMo ti ni ireti t’o daju,

Ninu ore-ofe Re

Olugbala mi mbe pelu mi,

O nrerin si omo Re

4

fMo l’ayo ti enu ko le so,

Ogo ayo na npo si

Bi kanga om’iye ninu mi ’

Jojumo l’o nru soke.