Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 277

Bikosepe a tun eniyan bi nipa omi ati nipa Emi on ki yoo le WO ijoba Olorun.

Meter: C.M.

Scripture: Jn. 3:5

1

fEyi l’ase nla Jehofa

Yoo wa titi lae

Elese b’iwo at’ emi,

K’a tun gbogbo wa bi.

2

pOkunkun y’o je ipa wa,

B’ a wa ninu ese;

A ki o ri ijoba Re,

Bi a ko d’ atunbi.

3

Bi baptisi wa je ’gbarun,

Asan ni gbogbo re;

Eyi ko le w’ ese wa nu,

Bi a ko tun wa bi.

4

Wo ise were ti a nse,

Ko ni iranwo Re;

Won ko s’okan wa di otun,

B’ awa ko d’atunbi.

5

fLO kuro ninu ese re

crJa ewon Esu nu;

fGba Kristi gbo tokantokan

ffIwo o d’atunbi.