Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 279

A WON omo Israeli si wi fun Oluwa pe, A wa ti se: ohunkohun ti o ba to li oju re ni ki ofi wa se; sa gba wa li oniyi, awa be o.

Meter: L.M.

Scripture: A. Oni. 10:15

1

pOluwa, sanu, dariji;

Da okan t’o yipada si;

Ki se pe anu Re tobi

Ijilese ko le ro mo O?

2

Ese mi po, jugbon ko le

Ju agbara ore Re lo:

Titobi Re ko ni opin,

Be ge ni k’a ri ife Re

3

pWe ese kuro l’okan mi,

Si mu okan ebi mi mo

Lokan mi ni feru na wa,

Ese ehin ro mi l’oju.

4

Ese mi f itiju jewo

Ete s’ofin at’ore Re:

Bi idajo Re yoo ba le,

Mo j’ebi, are niTire.

5

pB’idajo kan Kan gb’emi mi,

L’oju ’kuuno da Ol’are,

B’a si ran mi lo s’iparun

Tito ni l’oju ofin Re*

6

Sibe, gba elese t’o ngbon,

Ti ireti re nra baba,

Bi o le r’ileri didun

Lati ba le n’nu oro Re