Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 28

Nitori Oluwa yio je imole ainipekun Fun O.

Meter: 8.8.8.D

Scripture: Isa. 60:20

1

mfJesu, bukun wa k’a to lo,

Gbin oro Re si wa lokan;

K’o si mu k’ife gbigbona

Kun okan ilowowo wa,

CrNigba yiye at’iku wa,

PJesu jare, se ‘mole wa.

2

mpIle ti su, orun ti wo,

‘Wo si ti siro iwa wa,

Die nisegun wa loni,,

Isubu wa lo p’apoju

3

mfJesu, dariji wa, fun wa

L’ayo ati eru mimo

At’okan ti ko l’abawon,

Ka ba le jo Ol’ajo tan.

4

mpLala dun, tori’Wo se ri;

Aniyan fere, O se ri,

Ma je k’a gbo t’ara nikan,

K’a ma bo sinu idewo

5

mpA mbe O ‘awon alaini,

F’elese at’awon t’a fe,

Je ki anu Re mu wa yo,

‘wo Jesu l’ohun gbogbo wa.

6

mfJesu bukun wa, ile su,

Tikara Re, wa ba wa gbe,

Angel’ ere nso ile wa

A tun f’ojo kan sunmo O