Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 283

Enyin to tijina rere nigba atijo ri li a mu yin sunmo tosi nipa eje Kristi.

Meter: 8.8.7. & Ref.

Scripture: Efe. 2:13

1

mfLekan mo jina s’Oluwa

Mo nfi ’wa mi bi ninu

Sugbon Jesu ti gba mi

CHORUS

ffA! bi yo ti dun to

Dun to dun to dun to

A! bi yo ti dun to

Ki Jesu ma gbe inu mi.

2

mpIbinu ati irunu

Ni ewon t’esu fi de mi

Jesu ti ja ide na.

3

crIfekufe kun' okan mi

Ati igberaga gbogbo

Ina Emi ti jo won

4

fMo bo lwowo irewesi

LOWO ’ko gbona ko tutu

ffE ba mi yin Oluwa.

5

fMo nkorin sa lojojumo

Mo njo mo si tun nfo soke

Nipa agbara Emi

6

mfEje ’yebiye we mi mo

Omi iye nsan ninu mi,

fIgbala mi di kikun.

7

fEyin ara at’ore mi

Tani ko fe igbala yi

Ofe ni lodo Jesu;