Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 284

Isun kan yio si silefun ati fun iwa aimo

Meter: C.M. & Ref.

Scripture: Sek. 13:1

1

mfIsun kan wa to kun feje,

T’oti’ha Jesu yo;

mpElese mokun ninu re,

O bo ninu ebi.

CHORUS

mfA sa l’ogbe, n’tori ’rekoja,

A si pa lara, n’tori ese wa,

crIna alafia wa mbe l’ara Re

mfIna Re lo nwo wa san;

mpA sa l’ogbe n’tori ’rekoja,

A sa l’ogbe n’tori ’rekoja,

ffIna Re lo nwo wa san,

mfIna Re nwo wa san.

2

pOle ni lor’agbelebu,

mfYO lati ri ’sun na,

mpBi mo kun fese bi tire,

crMo le we n’n’ eje na.

3

mf’Gba mo figbagbo r’isun na

crTi nsan fun eje Re

fIrapada d’orin fun mi,

Ti un o ma ko titi.

4

fAgbara to wa n’n’eje yi

Yo wa titi laelae,

ffTit’awon eni ’rapada,

Y o bo sinu ogo.