Hymn 287
Ati ninu olanla Re ma gesin lo .
Meter: L.M.
Scripture: OD. 45:4
1
fM ag’esin lo l’olanla Re,
Gbo! gbogb’ aye nke,
“Hosana”
mpOlugbala, Ma lo pele
Lori im’ope at’aso.
2
fMag’esin lo l’olanla Re,
pMa f irele g’esin lo ku;
crKristi, ’segun Re bere na
fLori ese ati iku.
3
fMag’esin lo l’olanla Re,
diOgun angeli lat’ orun
pNfiyanu pelu ikanu
Wo ebo to sun mole yi.
4
fMa g’esin lo l’olanla Re,
mfIja ikehin na de tan,
fBaba lor’ite Re lorun
Nreti ayanfe Omo Re.
5
fMag’esin LO l’olanla Re,
pMa firele g’esin lo ku,
ppF’ara da irora feda,
fLeyin na nde, k’O ma joba.