Hymn 289
Lati enu awon omo owo ati omo omu ni Iwo ti mu iyin pe
Meter: 7.7.7.7. & Ref.
Scripture: Mat. 21:16
1
mfAwon ewe Salemu,
fKorin yin oko Jesu,
Awa ewe t’isiyi,
Jumo yin Olugbala
CHORUS
fGbo, b’awon ewe ti nko
Hosana si Oba wa.
2
mfA ko wa k’a f’Oluwa,
K’asi ma ka oro Re,
crA f ona orun han wa!
fOgo ni fun Olorun!
3
fK’oluko, t’agba t’ewe,
Jumo gbe orin na ga,
ffLoke-loke, k’o ma ho
Ki Hosana de orun.