Hymn 297
Nigbana ni Jesu ba Won wa si ibikan ti a npe ni Getsemane.
Meter: L.M.
Scripture: Mat. 26:36
1
mpOganjo gan l’oke Olif,
Awon irawo si ti wo:
Oganjo gan nisisiyi
pKrist’ nikan ngbadura l’ogba.
2
mpOganjo gan lair’enikan,
Jesu nikan ba eru ja;
Omo-eyin t’O fe papa
Ko nani ibanuje Re
3
mpL’oganjo fese elomi,
Eni kanu nsokun n’n eje.
pSibe, en’ t’o wole l’anu
Olorun ko je d’ehin Ko
4
mpOganjo gan; lati papa
fA ngb’orin awon angeli.
crOrin titun t’a ko gbo ri
pL’o tu Olugbala l’ara