Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 299

Sa ro ti Eniti O farada iru isoro-odi yi lati odo awon elese si ara won.

Meter: C.M.

Scripture: Heb. 12:3

1

mpWo Olugbala araye

T’ A kan m’agbelebu!

Ifena ti po to, t’O fe

Lati wa ku fun O!

2

pGbo’kerora Re! bo ti ke,

Isele nla-nla se;

crIkele tempil pin me j i,

ppOkuta re sisan.

3

mfOpari! Ati san’gbese,

diO ke, ‘ ‘gba emi Mi”;

Wo b’O ti te ori Re ba,

ppO te ba O si ku.

4

crLaipe, y’O ja ide iku

Ogo Re y’o si tan;

fOlugbala, ko Ji ’rora;

ffTabi ’fe bi Tire.