Hymn 30
Nitori ojo nlo.
Meter: 7.6.7.6.8.8
Scripture: Jer. 6:4
1
Ojo oni koja lo,
A dupe, Oluwa,
Jo, gba wa lowo ese
Ni wakati oru,
DiJesu, jo, f’iso Re so wa,
CrSi mu wa la oru yi ja.
2
mfAyo oni koja lo,
A gb’okan wa s’oke
Jo, ma je k’a n’ikose
Ni wakati oru;
DiJesu, jo fun wa n’imole,
CrSi mu wa la oru yi ja
3
mfLala oni koja lo,
A fi orin yin O,
Jo, ma je k’a ri ewu
Ni wakati oru;
DiJesu, jo f’is Re so wa,
CrSi mu wa la oru yi ja.
4
mfS’Olupamo wa, Baba,
Nitori; Wo l’O mo
Gege b’ewu ti po to,
Ti a o ba pade;
DiJesu, Olufe, gbo ti wa,
CrSi mu wa la gbogbo won ja.