Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 304

E duro nihinyi ki e si ma Bami sona.

Meter: C.M.

Scripture: Mat. 26:38

1

pOkun l’ale tutu n'ile

Nibi Kristi wole;

pOgun Re bi iro eje

Ninu ’waya ija.

2

mf“Baba gb’ago kikoro yi

B’O ba se ife Re,

Bi beko, emi o si mu

Ife Re nik’ase.”

3

Elese lo WO l’agbala

Eje mimo wonni;

pO r’eru ’wuwo ni fun o

O si mu ’po ’rele.

4

KO lati gbe agbelebu,

Se ife ti Baba;

Nigba idanwo sun mo le

ffJi, sora, gbadura.