Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 305

Alabapin ninu iya Re.

Meter: C.M.

Scripture: Fili. 3:10

1

pKi Jesu ha nikan jiya,

K’araye lo l’ofo?

pIya mbe folukuluku

crIya si mbe fun mi.

2

mfAyo awon mimo tito

T’won banuje l’aye;

Nisiyi won ngbe ’nu ife

fAti ayo pipe.

3

pEm’o ru agbelebu mi

Tit’iku y’o gba mi,

mf’Gbana un o lo ’le lo d’ade

Tor’ ade mbe fun mi.