Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 307

O fi emi Re lelefun awon agutan Re.

Meter: 6.6.6.6.6.6.

Scripture: Jn. 10:11

1

O f ara Re fun mi,

pO ku nitori mi,

crK’O le ra mi pada,

Ki nle jinde n’n’ oku,

O fara Re fun mi,

pKi l’emi se fun O?

2

O F’OJO aye Re,

Se wahala fun mi;

Ki emi ba le mo

Adun ayeraye,

O L’OPO odun fun mi

Mo lo kan fun O bi?

3

Ile ti Baba Re

At’ite ogo Re

O fi sile w’aye

O d’alarinkiri

O fi ’le ’tori mi,

Mo fi nkan fun O bi?

4

pO jiya po fun mi,

Ti enu ko le SO

O jijakadi nla

cr’Tori igbala mi,

O jiya po fun mi,

mpMo jiya fun O bi?

5

fO mu igbala nla

Lat’ile Baba Re

Wa lati fifun mi,

O si dariji mi.

O m’ebun wa fun mi

Kin’ mo mu wa fun O?

6

mfUno f ara mi fun O,

Un o f’aye mi sin 0.

Uno d’iju si aye,

Uno wo ohun t’orun,

Mo f’ohun gbogbo mi

F’Oluwa, Oba mi.