Hymn 312
Ko ha kan nyin bi, gbogbo enyin ti nkoja?
Meter: 5.5.11.D.
Scripture: E. Jer. 1:12.
mfE yin ti nkoja,
Ya s’odo Jesu;
mpO ha s’asan fun yin bi Jesu-ba ku;
Olurapada,
Onigbowo yin,
pWa, wo bi ’banuje kan ri bi Tire.
crEje Re s’etu
Fun ese t’eda,
mpBaba se Omo Re n’ise nitori yin,
Oluwa, ni’jo
Ti ‘binu Re ru,
K’ese yin l’Od’agunta t’O ko won lo
mfO duro fun wa,
E wa je ’pe Re
E fi ’yanu wole lab’agbelebu!
E gb’oju woke,
Bi Jesu ti nke,
pO jiya laibohun; Eni aiku ku.
mfO s’etu f’ese
Ti ki se Tire
O san igbese yin, O sise fun yin;
Gbogbo yin le pin N’nu alafia Re,
mpEni bebe pe; “Baba mi dariji'’
mfO bebe fun wa Lor’agbelebu,
Adura Re gba, elese domnira;
Emi elese
T’o gba Jesu gbo,
Mo wa gba ‘fiji t’O Ki o fi du mi.
mpMa toro ’fiji;
Nitori mo je
Elese t’o gba oruko Jesu gbo
O ra or’ofe
Ti mo gba mora;
Baba, Iwo mo pe O ku dipo mi.
crIku Re setu;
’Wo Alagbawi mi
Gbo b’eje t’a ta ’le ti mbebe fun mi;
O ra mi pada,
’Gba t’O ku lor’igi;
fEmi Re t’O fi lele da mi lare.