Hymn 317
A kegan Re, a si koo lodo awon eniyan.
Meter: 7.7.7.8.
Scripture: Isa. 53:3.
1
E ni ’kanu! - oruko
crT’a npe Omo Olorun;
fT’O wa gba elese la!
ffAleluya! Olugbala!
2
mfO farada eleya,
Ada lebi nipomi!
Eje Re setu fun mi
ffAleluya! Olugbala!
3
crOto s’elese ni wa;
Alailabawon li On:
Nje loto lO setutu?
ffAleluya! Olugbala!
4
mpA gbe ko sori igi,
pOkepe, Oti pari!
A gbe ga lorun n’isiyi:
ffAleluya! Olugbala!
5
mf’Gbat’ Oba Ogo b'a de,
’Lati m’eni Re re ’le
Ao ko orin yi lotun
ffAleluya! Olugbala!