Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 324

Awon wonyi ni not Odo-aguntan Lehin, nibikibi ti nre.

Meter: C.M.

Scripture: Ifi 14:4

1

mfE je k’a to Jesu wa lo,

Ni agbala nla ni,

Nibiti o NLO gbadura,

pNibit’ o nlo kanu

2

K’a wo b’O ti dojubole,

pT’O nmi imi edun,

Eru ese wa l’O gberu.

Ese gbogbo aye.

3

Elese, wo Oluwa re,

Eni mimo julo;

Nitori re ni Baba ko O,

Aye si d’ota Re.

4

mfIWO o ha wo laironu,

Lai k’ese re sile?

pOjo idariji nkoja,

Ojo igbala nlo.