Hymn 327
A woran re yio te mi lorun nigba ti mo baji
Meter: 8.7.8.3
Scripture: OD. 17:15.
1
fL ’ oruwo ojo ajinde,
T’ara t’okan yo pade,
Ekun, ’kanu on irora
Yo dopin.
2
pNihin, won ko le sai pinya
Ki ara ba le simi
Ko si fi idake roro
Sun fonfon.
3
Fun ’gba die ara are yi
La gbe sibi ’simi re
crTiti di imole oro
Ajinde.
4
mfSugbon okan to ns’asaro
To si ngbadura kikan
Yo bu s’orin ayo lojo
Ajinde.
5
mfAra at’okan yo dapo,
Ipinya ko ni si mo;
crWon o ji l’aworan
Krist’ ni ’Telorun.
6
fA! ewa na at’ayo na
Yo ti po to lAjinde!
Yo duro borun ataye
Ba fo lo.
7
mfL’oro ojo ajinde wa
'Boji yo m’oku re wa;
Baba, iya, omo, ara Yo pade.
8
Si ’dapo ti o dun bayi
diJesu masai ka wa ye;
pN’nu’ku,’dajo, kalero m’a Gbelebu.