Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 332

Ji ohun elo orin mimo ati duru emi tikara mi yio si ji ni kutukutu.

Meter: D.C.M.

Scripture: OD. 108:2.

1

fJi, ji okan ayo ji, ji.

Oluwa re jinde

LO ’boji Re, ko si mura

Okan ati korin;

Gbogbo eda lo si tiji,

Ti won nkorin didun,

Itanna ’ kini to ko tan

Leba odo lo hu.

2

mfIsudede aye yo lo

Lojo ajinde yi;

Iku ko si mo ninu

Kristi Iboji ko n’ipa

fNinu Kristi la nwa, ta nsun,

T’a nji, ta si ndide;

pOmije t’iku mu ba wa

crNi Jesu yo nu nu.

3

fKi gbogbo eye at’igi

At’itanna ti ntan,

Ki won SO ti isegun Re

Ati t’ajinde Re,

Papa, e gb’ohun yin soke

E bu sorin ayo,

Eyin oke, e si gberin

Wipe, “Iku ti ku”

4

ffOkan ayo, eji, e wa

Oluwa t'O jinde.

E yo ninu ajinde Re,

K’oro Re tu yin n’nu;

E gb’ohun yin soke, k’eyin

Eni t'O ji dide;

L’ohun kan ni ka gberin pe

“Jesu jinde fun mi”.