Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 338

Ko ha ye ki Kristi ki o jiya nkan Wonyi ki o si WO inu ogo Re lo?

Meter: 10.11.11.11. & Ref.

Scripture: Lk. 24:26.

1

mfTire ni ogo, Omo nla Baba

Titi ni ’segun na t’O ni lori ’ku

Awon angeli to y’okuta na kuro

F’aso ogbo na lele niboji Re

CHORUS

fTire ni ogo Omo nla Baba

Titi ni’segun na t’O ni lori'ku

2

fWo! Jesu ji dide ninu oku

O si fi ’fe tu eru okan wa ka

K’ijo Olorun f’ayo korin ’segun

Oluwa mbe, iku so oro re nu.

3

mfAigba O gbo bila, Kristi Jesu

Laisi Re ko s’iye, ran aini wa lowo

Mu wa j’asegun lo nipa ife Re.

Tit’ ao koja Jordan sile wa orun.