Hymn 343
Awon Oba aye kese jo, ati awon ijoye ngbimo po si Oluwa.
Meter: 6.6.6.6.8.8.
Scripture: OD. 2:2.
1
ffB’elese s’owopo,
Ti won nde s’Oluwa,
Dimo si Kristi Re,
Lati gan Oba na,
B’aye sata,
Pelu Esu,
Eke ni won,
Won nse lasan.
2
fOlugbala joba!
Lori oke Sion;
Ase ti Oluwa,
ffGbe Omo Tire ro:
Lati boji
O ni k’O nde,
K’O si goke,
K’O gba ni la.
3
mfF’eru sin Oluwa,
Si bowo fase Re;
F’ayo wa sodo Re,
F’iwariri duro;
pE kunle fun Un
K’e teriba;
Sot’ipa Re,
Ki Omo na!