Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 344

Wo ti di igbekun ni igbekun LO

Meter: 8.8.6.D.

Scripture: OD. 68:18.

1

mfJesu t’Oku, k’Ogb’aye la

Jinde kuro ninu oku,

Nipa agbara Re;

ffA da sile lo wo iku,

O d’igbekun n’igbekun lo,

crOye, k’O ma kumo.

2

Eyin om’Olorun, e wo

Olugbala ninu ogo;

O ti segun iku:

Ma banuje, ma beru mo,

O nio pese aye fun yin,

Yio mu yin lo ‘le.

3

mfO foju anu at’ife

Wo awon ti O ra pada;

Awon ni ayo Re;

O ri ayo at’ise won,

O bebe ki won le segun,

ffKi won ba joba lae.