Hymn 347
Emi o si se awon ati ibiti o yi oke mi ka ni ibukun.
Meter: 8.7.8.7.D.
Scripture: Esek. 34:26
1
mfOlorun wa mbe larin wa,
Lati bukun gbogbo wa,
Wo oju orun b’o ti su
Yo ro ojo ibukun;
fK’o de Oluwa, a be O
Je k’ojo Ibukun de;
Awa nduro, awa nduro,
M’okan gbogbo wa soji
2
mfOlorun wa mbe larinwa
Ninu ile mimo yi,
Sugbon a nfe ‘tura okan wa
At’opo o’ofe Re
3
Olorun wa mbe larin wa,
K’a mu ebe wa t’O wa,
Ki ife Re ba le gberan
Lati m’okan wa gbona.
4
Jesu fi ’bere wa fun wa,
B’ati fi ‘gbagbo kunle,
diJo si ferese anu Re
K’o tu ’bukun sori wa.