Hymn 352
Oluwa, mu ise Re soji.
Meter: C.M.
Scripture: Hab.3:2.
1
mfJesu Olugbala aye,
A ntoro ’bukun Re,
si ’lekun aitase sile
fun ’wasu oroRe.
2
mfKo awon to nu bo sile,
Gba won lowo esu;
crJeki won ri itewogba,
Ki won mo ’gba anu.
3
mfOlufe okan: Iwo mo
Riri ohun t’O ra;
Wa f’ara han awon Tire
Pelu gbogb’ ogbe Re,
4
Mu ki okan won lile ro,
Iwo t’O ku f’eda;
Fi eri if?e Re han won;
Ese, owo, iha.
5
pEse Re la kan mo igi,
k’Otese won mole;
A na apa Re lati gba
Awon ti won pa O.
6
Iha Re ni’bi orisun,
Nibi gbogbo eda
crLe lo mu n’nu omi iye,
Ki won we ’ra won mo.
7
mf’Wo nfe f’eje Re jeri pe
Otito l’oro na;
Ogbe Re nke s’elese pe:
pMo jiya yi fun o.