Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 353

E gbe ori nyin soke enyin enu ona ki Oba Ogo WO inu ile wa.

Meter: C.M.

Scripture: OD 24:7

1

fAgbe ilekun wura ro,

A si si won paya;

Oba Ogo si ti wole

Lo s’odo Baba Re

2

mfOluwa’Wo ti saju lo

Pese aye fun wa,

Ki a ba le wa lodo Re,

Lati w’oj’ Olorun

3

Imole t’o logo ntan lae

Li ona aye wa;

Imole to tan s’okunkun

diTi ko je ka ri O.

4

mfJowo gbe okan wa soke,

F’ore-ofe fun wa

Ba ti nrin kiri l’aye yi

Ka ni ’sura lorun.

5

fKi ireti at’ife wa

Le ma wal’odo Re;

Ma gbe ’nu wa, ki a le wa

Ninu Re titi lae.