Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 357

IWO ti goke si ibi giga.

Meter: 7.6.7.6.D.

Scripture: OD. 68:18.

1

fKristi, l’ehin isegun

IWO ti goke lo;

Kerub’ at’ogun orun

Wa sin O goke lo;

mfK’aye so ’tan na jade,

crImanueli wa,

fTi s’ara iy’ara wa,

Gori ite Baba.

2

mf’Lekun orun si sile,

IWO ha le gbagbe

Awon to fe 0, Jesu

Ti iwo lat’Olifi?

L’okan aya Re la ko

Oruko gbogbo si;

Alufa l’aye, l’orun,

Okan nal’ailopin.

3

mfNibe lo duro, to nso di

Agbara eje Re;

O mbebe fun elese,

’Wo alagbawi wa,

pGbogbo ayida aye

T’ayo, t’aniyan wa

crN’iwo nse iyonu si,

T’iwo si mbebe fun.

4

pNitori itoye nla

Ti agbelebu Re,

K’O fi Emi Mimo Re

So ofo wa d’ere,

Nipa igbiyanju wa

Okan wa o goke;

Lati ba O gbe titi,

Li,ayo ailopin.