Hymn 358
E ho iho ayo si Oluwa, Enyin ile gbogbo.
Meter: 6.6.6.6.8.8.
Scripture: OD. 100:1.
1
fOlorun goke lo
Pelu ariwo nla,
Awon ipe orun
Nf’ayo angeli han;
ffGbogbo aye yo, ke gberin
E f’ogo fun Oba Ogo.
2
mpO j’eniyan laye,
fOba wa ni loke;
Ki gbogbo ile mo
Ife nla Jesu wa.
3
fBaba fi agbara
Fun, Jesu Oluwa;
Ogun angel’ mbo O;
On l’Oba nla orun.
4
fL’or’ite Re mimo,
O gb’opa ododo;
Gbogbo ota Re ni
Yio ku LO bere.
5
fOta Re l’ota wa;
Esu, aye,ese;
Sugbon yo rehin won,
Ijoba Re yo de.
6
fTiti gbogbo aye
Ta fododo tun bi
Yo ba ogun orun
Gbe orin ayo nla.