Hymn 361
Emi nlo, lati pese aye sile fun yin.
Meter: 10.10.10.10.
Scripture: Jn. 14:2.
1
fE gbo iro orin ayo orun,
Orin ayo ti isegun Jesu;
Gbogbo ota l’o teri won ba fun,
pEse, iku, isa-oku pelu.
2
fO se tan lati lo gba ijoba,
Fun Baba, Olorun ohun gbogbo;
O se tan lati lo gba iyin nla,
T’o ye Olori-ogun ’gbala wa.
3
pOhun ikanu ni lilo Re, fun
Awon ayanfe Omo-eyin Re
fE ma se konnu l’oro itunu.
“Emi nlo pese aye yin sile''
4
Orun gba LO kuro leyin eyin,
Awosanma se Olugbala mo;
ffAwon Ogun-orun ho fun ayo,
Fun bibo Kristi Oluwa ogo.
5
mpE mase ba inu yin je rara
Jesu, ireti wa, yio tun wa,
fYoo wa mu awon eeyan Re lo
Sibiti won o ba gbe titi lae.