Hymn 363
Bi o ti nsure fun nwon, a ya a kuro LODO nwon a si gbe e LO si Qrun.
Meter: C.M.
Scripture: Lk. 24:51.
1
A ha iho ayo mimo
S’Olorun Oba nla
K’ile gbogbo lo ahon won
K’o si ko ’rin ’'segun.
2
Jesu Oluwa wa goke
Eso orun yika,
Won ba goke bi O ti nlo
Pelu iro fere.
3
B’Angeli ti nyin Oba won
K’eda ko orin na:
Ki aye korin ola Re:
O joba gbogb’ aye
4
F’iberu nla wa iyin Re
Fi oye korin na,
Ma fi ahon etan fun u
Nipa iyin eto.