Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 366

Sugbon enyin o gba agbara, nigbati Emi Mimo ba ba le nyin.

Meter: 8.7.8.7. & Ref.

Scripture: Ise. A. 1:8.

1

mf’Gbat’ agbara Olorun de,

Li ojo Pentikosti,

Sa if oju s’ona pari,

’Tori won ri Emi gba.

CHORUS

ffRan agbara, Oluwa,

Ran agbara, Oluwa,

Ran agbara, Oluwa,

Ki O si baptis’ wa.

2

fEla ’han ina ba le won

Won si wasu oro na,

OPOLOPO eeyan gbagbo

Won yipada s’Olorun.

3

crA nw’ona fun Emi Mimo

Gbogbo wa f ohun sokan

Mu ’leri na se, Oluwa,

Ti ase nin’oro Re

4

fJo, fi agbara Re kun wa,

Fun wa ni ’bukun ta nfe;

Fi ogo Re kun okan wa,

Ba ti nfi ’gbagbo bebe