Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 368

Emi o tu Emi mi jade sara eniyan gbogbo.

Meter: C.M.

Scripture: Joe. 2:28.

1

mfEmi Mimo, mi s’okan wa,

Ka mo agbara Re;

crOrisun Emi ’so tele,

T’imole at’ife

2

mfEmi Mimo l’agbara Re

L’awon Woli sise;

Iwo lo,nfi oto han wa,

Ninu iwe mimo

3

mfAdaba orun, na ‘ye Re

Bo okun eda wa:

Jeki ’mole Re tan sori,

diEmi aisoto wa

4

mfA o mo. Olorun daju

B’Iwo ba mbe n’nu wa

Ao mo ‘jinle ife mimo

Pelu awon Tire.