Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 37

E ma sin Oluw Ewa iwa mimo.

Meter: 13.10.13.10

Scripture: OD 96:9

1

mfE sin Oluwa ninu ewa iwa mimo

Wole fun k’esi pokik’ ogo Re

Pelu wura ‘gboran ati turari ‘rele

W wole fun Un k’e si juba Re.

2

Gbe eru aniyan yin lele lese Re

Y’o si ti ka Re ba yin gbe d’ori;

Y’o tu o ninu, yo si gbo adura re,

Y’o to ‘sise re bo ti to fun o

3

Ma beru lati wo agbala Re, pelu

Kiun ninu oro t’o le pe n tire;

CrEwa otito ati ife owuro,

Febo wonyi la nbere lowo re

4

mfB’a tile m’awon wonyi wa ni ‘wariri

CrOn y’o gba won l’oruko to sowon,

Fayo owuro y’o dipo ekun ale

Ireti kikun y’o dipo eru.

5

mfE sin Oluwa ninu ewa iwa mimo,

Wole fun k’e si pokik’ogo Re

Pelu wura ‘gboran ati turari ‘rele.

E wole fun Un ke si juba Re.