Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 370

Emi Olorun si nrababa loju omi.

Meter: C.M.

Scripture: Gen. 1:2.

1

f’G banit’ Olorun sokale,

O wa ni ibinu,

Ara si nsan niwaju Re,

Okunkun oun ina.

2

pNigbat’O wa nigba keji,

O wa ninu ife;

ppEmi Re si ntu ni lara

B’afefe owuro

3

fIna Sinai ijo kini,

T’OWO re mbu s’oke,

mpSokale jeje bi ade,

Si ori gbogbo won.

4

fBi ohun eru na ti dun

L’eti Israeli,

B’iro ipe, ti angeli

Wariri lati gbo

5

mfBe gege nigbat’ Emi wa

Bale awon Tire,

crIro kan si ti orun wa;

Iro iji lile.

6

fO nkun ijo Jesu, o nkun

Aye ese yi ka,

mpL’okan alaigboran nikan

Ni aye ko si fun.

7

mfWa, ogbon, Ife at’ Ipa;

Fun wa leti igbo;

pKa ma so akoko wa nu;

Ki ’fe Re le gba wa.