Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 374

Emi o si fi Emi titun sinu yin.

Meter: 7.7.7.

Scripture: Esek. 11:19.

1

mpWa, Parakliti mimo,

Lat’ ibugbe Re orun;

crRan itansan ’mole wa

2

mfBaba talaka, wa ’hin,

Olufunni l’ebun, wa,

Imole okan, jo wa.

3

pBaba Olutunu, wa

Alejo toto f’okan,

Pelu itura Re, wa.

4

mf’Wo n’isimi n’nu lala

Iboji ninu oru,

Itunu ninu’ponju.

5

p’Wo’ mole to gara

crTan sinu aye awon

Eniyan Re Oloto.

6

Laisi Re, kil’eda je?

Ife at’ero mimo

Lat’ odo Re wa ni won

7

pEleri, so di mimo

Agbogbe, masai wo san,

Alaiseso mu s’eso

8

Mu okan tutu igboan,

M’agagidi, teriba,

Pe asako wa jeje

9

crF’emi ‘jinle Re meje

Kun awon oloto Re,

F’agbara Re s’abo won.

10

fRan or’ofe Re, sihin,

Ekun igbala l’aye

At’alafia l’orun