Hymn 375
Nitori eso Emi wa ni ti ohun rere gbogbo, ati ododo, ati otito.
Meter: 8.8.8.D.
Scripture: Efe. 5:9.
1
mfWa, mi si wa, Emi Mimo,
Tan ’ na orun si okan wa;
Emi a fororo yan ni
Ti f’ebun meje Re fun ni;
Ise nla Re at’oke wa
N’itunu, iye, ina, ife.
2
F’imole Re igba gbogbo
Le okunkun okan wa lo.
mfF’ororo ore-ofe Re
Pa oju eri wa, ko dan;
diL’ota jina si ’bugbe wa:
pIre n’igbe’ biti’ Wo nso
3
mfKo wa, ka mo Baba, Omo,
Pelu Re li okansoso
crTiti aye ainipekun,
Ni k’eyi ma je orin wa;
fLae, iyin, eye ni fun O .
Baba, Omo, Emi Mimo.