Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 38

E wa, e je ki a korin si Oluwa.

Meter: C.M

Scripture: OD95:1

1

mfE wa k’a korin s’Oluwa,

Olukuluku wa;

FKi a ho iho ayo si

Apata ‘gbala wa.

2

e je k’a wa siwaju Re

Pelu ‘yin at’ope;

Ka ko orin pel’ore ofe,

Ka si yo ayo nla.

3

ffOlorun yi tobi l’Oba

J’awon orisa lo;

Gbogbo’aye wa nikawo Re

At’awon oke nla

4

fTire li awon okun nla,

On ni O si da won;

Ati ‘yangbe ile pelu,

Owo Re lo si da.

5

mfE wa, e je ki a wole

Ki a teriba fun,

Ki a si kunle niwaju

Oluwa Eleda.