Hymn 385
Emi otito ni yio si wa ninu yin.
Meter: 7.7.7.D.
Scripture: Jn. 14:17.
1
crEmi Ore, bami gbe!
Emi o si d’olore,
Pelu oro isore
Ni un o fi emi Re han,
N’igboya at'irele
L’emi o soro Kristi
2
diEmi Oto, bu min gbe!
Emi o si d'oloto,
Pelu ogbon to daju
Ni un o fi emi Re han
Ni ife arakunrin
Ni un o s’oto Oluwa
3
mpEmi Tutu, ba mi gbe!
Emi o si di tutu:
f’okan mi mo b’itanna
Li akoko idanwo;
Si sile n’gba orun nran,
F’orun, didun yin ’fe Re
4
mfEmi Ipa, ba mi gbe!
Emi o si lagbara,
Agbara lati bori
Nibi ti ipa eeyan pin,
Un o si ma tesiwaju
Ninu ‘reti titi lae
5
fEmi Mimo, ba mi gbe!
Emi o si di mimo;
Emi o ya fun ese
Emi yan ohun ’re;
Ohun ti mo ba si ni,
Un o fun Eni to dami.