Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 386

Gbogbo won si kun fun Emi Mimo.

Meter: 8s.7s.

Scripture: Ise A. 2:4.

1

fBaba wa orun, a wade,

pAwa alailagbara:

crFi Emi mimo Re kun wa

K’o so gbogbo wa d’otun

CHORUS

fWa! Emi Mimo jare wa!

F’ede titun s’okan wa

Ebun nla Re ni l’a ntoro

T’ojo nla pentikpsti

2

fRanti ileri Re Jesu,

Tii Emi Re s’ara wa;

Fi alafia Re fun wa

T’aye ko le fi fun ni,

3

fAdaba orun! ba le wa

fFi agbara Re fun wa;

Ki gbogbo orile ede

Teriba f’Olugbala,