Hymn 388
Ongbe re ngbe okan mi, Bi ile gbigbe.
Meter: 7.6.7.6.D.
Scripture: OD. 143:6.
1
mfEmi Mimo sokale,
Fi ohun orun han;
K’o mu imole w’aye,
Si ara eniyan
K’awa t’a wa l’okunkun,
Ki o le ma riran,
p’Tori Jesu Kristi ku
Fun gbogbo eniyan
2
K’o fi han pe elese
Ni emi nse papa;
K’emi k’o le gbeke mi
Le Olugbala mi
Nigbati a we mi nu
Kuro ninu ese
Emi o le fi ogo
Fun Eni-mimo na.
3
fK’o mu mi se aferi
Lati to Jesu lo;
K’o joba ni okan mi.
K’o so mi di mimo;
Ki ara ati okan,
K’o dapo lati sin
Olorun Eni-mimo
Meta-lo-kan-soso.